NEWS

Toyin Abraham Pens Sweet Message To Her Husband On His Birthday

By

on

“Oko mi, ololufe mi, olowo ori mi @kolawoleajeyemi
Iwo ni eledumare fi se aso bo ihoho mi,
Iwo ni ete ti o je ki eyin mi di apoti isana
Iwo ni ejika ti ko je ki aso o ye lorun mi
Kolawole, iwo ni orun ti o gbe ori emi Toyin duro

Ni ojo eni to o je ayajo ojo ti a bi e saye, ni agbara eledumare, ire gbogbo ma wa e ri

Rere ni oju owo n ri, rere bayi ni oju e ma ma ri.
Eyan bi esu, esu bi eyan ti o ma n fi ikoro si nkan ti o n dun o ni fi ikoro si Ife wa ni agbara Olorun

Iwo ni irawo owuro mi, Irawo e o ni wo okunkun

Akolawole, Odun tuntun yi a san e s’owo, a san e s’omo, a san e si alafia ati emi gigun.
Happy birthday my love. Ife wa, titi laye laye ni.
I love you now and forever.”

Read Also: Student Behind Viral Crying Meme Speaks Up About How The Photo Was Taken (video)

See the full post below:

View this post on Instagram

Oko mi, ololufe mi, olowo ori mi @kolawoleajeyemi Iwo ni eledumare fi se aso bo ihoho mi, Iwo ni ete ti o je ki eyin mi di apoti isana Iwo ni ejika ti ko je ki aso o ye lorun mi Kolawole, iwo ni orun ti o gbe ori emi Toyin duro Ni ojo eni to o je ayajo ojo ti a bi e saye, ni agbara eledumare, ire gbogbo ma wa e ri Rere ni oju owo n ri, rere bayi ni oju e ma ma ri. Eyan bi esu, esu bi eyan ti o ma n fi ikoro si nkan ti o n dun o ni fi ikoro si Ife wa ni agbara Olorun Iwo ni irawo owuro mi, Irawo e o ni wo okunkun Akolawole, Odun tuntun yi a san e s’owo, a san e s’omo, a san e si alafia ati emi gigun. Happy birthday my love. Ife wa, titi laye laye ni. I love you now and forever❤️❤️❤️❤️❤️

A post shared by TOYIN ABRAHAM???????????????????????????? (@toyin_abraham) on

Recommended for you